Mátíù 23:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “Ẹ gbé, ẹ̀yin akọ̀wé òfin àti Farisí, ẹ̀yin alágàbàgebè! torí pé ẹ̀ ń fọ ẹ̀yìn ife àti abọ́ mọ́,+ àmọ́ wọ̀bìà*+ àti ìkẹ́rabàjẹ́ kún inú wọn.+ Lúùkù 11:38, 39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àmọ́ ó ya Farisí náà lẹ́nu nígbà tó rí i pé kò kọ́kọ́ wẹ ọwọ́* kó tó jẹun.+ 39 Ṣùgbọ́n Olúwa sọ fún un pé: “Ẹ̀yin Farisí, ẹ̀ ń fọ ẹ̀yìn ife àti abọ́ mọ́, àmọ́ wọ̀bìà àti ìwà burúkú kún inú yín.+
25 “Ẹ gbé, ẹ̀yin akọ̀wé òfin àti Farisí, ẹ̀yin alágàbàgebè! torí pé ẹ̀ ń fọ ẹ̀yìn ife àti abọ́ mọ́,+ àmọ́ wọ̀bìà*+ àti ìkẹ́rabàjẹ́ kún inú wọn.+
38 Àmọ́ ó ya Farisí náà lẹ́nu nígbà tó rí i pé kò kọ́kọ́ wẹ ọwọ́* kó tó jẹun.+ 39 Ṣùgbọ́n Olúwa sọ fún un pé: “Ẹ̀yin Farisí, ẹ̀ ń fọ ẹ̀yìn ife àti abọ́ mọ́, àmọ́ wọ̀bìà àti ìwà burúkú kún inú yín.+