Mátíù 20:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jésù dáhùn pé: “Ẹ ò mọ ohun tí ẹ̀ ń béèrè. Ṣé ẹ lè mu ife tí mo máa tó mu?”+ Wọ́n sọ fún un pé: “A lè mu ún.” Jòhánù 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ Jésù sọ fún Pétérù pé: “Fi idà náà sínú àkọ̀ rẹ̀.+ Ṣé kò yẹ kí n mu ife tí Baba fún mi ni?”+
22 Jésù dáhùn pé: “Ẹ ò mọ ohun tí ẹ̀ ń béèrè. Ṣé ẹ lè mu ife tí mo máa tó mu?”+ Wọ́n sọ fún un pé: “A lè mu ún.”