-
Mátíù 26:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Ó tún lọ gbàdúrà lẹ́ẹ̀kejì, ó sọ pé: “Baba mi, tí kò bá ṣeé ṣe kí èyí kọjá lọ àfi tí mo bá mu ún, jẹ́ kí ìfẹ́ rẹ ṣẹ.”+