Máàkù 14:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Àmọ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n dúró nítòsí fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+ Lúùkù 22:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ọ̀kan nínú wọn tiẹ̀ ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ ọ̀tún dà nù.+ Jòhánù 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ni Símónì Pétérù tó ní idà bá fà á yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ ọ̀tún dà nù.+ Málíkọ́sì ni orúkọ ẹrú náà.
47 Àmọ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n dúró nítòsí fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+
10 Ni Símónì Pétérù tó ní idà bá fà á yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ ọ̀tún dà nù.+ Málíkọ́sì ni orúkọ ẹrú náà.