Mátíù 26:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Àmọ́ wò ó! ọ̀kan lára àwọn tó wà pẹ̀lú Jésù na ọwọ́ rẹ̀, ó fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+ Máàkù 14:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Àmọ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n dúró nítòsí fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+ Lúùkù 22:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ọ̀kan nínú wọn tiẹ̀ ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ ọ̀tún dà nù.+
51 Àmọ́ wò ó! ọ̀kan lára àwọn tó wà pẹ̀lú Jésù na ọwọ́ rẹ̀, ó fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+
47 Àmọ́ ọ̀kan lára àwọn tí wọ́n dúró nítòsí fa idà rẹ̀ yọ, ó sì ṣá ẹrú àlùfáà àgbà, ó gé etí rẹ̀ dà nù.+