Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+ Máàkù 15:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bákan náà, wọ́n kan àwọn olè méjì mọ́gi lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+ Lúùkù 23:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí wọ́n ń pè ní Agbárí,+ wọ́n kàn án mọ́gi níbẹ̀, àwọn ọ̀daràn náà sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+ Jòhánù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ibẹ̀ ni wọ́n ti kàn án mọ́gi+ pẹ̀lú ọkùnrin méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Jésù sì wà ní àárín.+
12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+
33 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí wọ́n ń pè ní Agbárí,+ wọ́n kàn án mọ́gi níbẹ̀, àwọn ọ̀daràn náà sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+
18 Ibẹ̀ ni wọ́n ti kàn án mọ́gi+ pẹ̀lú ọkùnrin méjì, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn wà ní ẹ̀gbẹ́ rẹ̀, Jésù sì wà ní àárín.+