Máàkù 15:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Àmọ́ Jésù ké jáde, ó sì gbẹ́mìí mì.*+ Lúùkù 23:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Jésù sì ké jáde, ó sọ pé: “Baba, ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé.”+ Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó gbẹ́mìí mì.*+ Jòhánù 19:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Lẹ́yìn tó gba wáìnì kíkan náà, Jésù sọ pé: “A ti ṣe é parí!”+ ló bá tẹ orí rẹ̀ ba, ó sì jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀.*+
30 Lẹ́yìn tó gba wáìnì kíkan náà, Jésù sọ pé: “A ti ṣe é parí!”+ ló bá tẹ orí rẹ̀ ba, ó sì jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀.*+