ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 31:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé.+

      O ti rà mí pa dà, Jèhófà, Ọlọ́run òtítọ́.*+

  • Mátíù 27:50
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Jésù tún ké jáde, ó sì jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀.*+

  • Lúùkù 23:46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 46 Jésù sì ké jáde, ó sọ pé: “Baba, ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹ̀mí mi lé.”+ Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó gbẹ́mìí mì.*+

  • Jòhánù 19:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Lẹ́yìn tó gba wáìnì kíkan náà, Jésù sọ pé: “A ti ṣe é parí!”+ ló bá tẹ orí rẹ̀ ba, ó sì jọ̀wọ́ ẹ̀mí rẹ̀.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́