Sáàmù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+Òní ni mo di bàbá rẹ.+ Mátíù 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Wò ó! Ohùn kan tún dún láti ọ̀run+ pé: “Èyí ni Ọmọ mi,+ àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.”+ Lúùkù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+ 2 Pétérù 1:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+
22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+
17 Torí ó gba ọlá àti ògo láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba, nígbà tí ògo ọlá ńlá sọ irú ọ̀rọ̀ yìí fún un* pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́ mi, ẹni tí èmi fúnra mi tẹ́wọ́ gbà.”+