Àìsáyà 42:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+ Mátíù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, wò ó! ìkùukùu* tó mọ́lẹ̀ yòò ṣíji bò wọ́n, sì wò ó! ohùn kan dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.+ Ẹ fetí sí i.”+ Lúùkù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+
42 Wò ó! Ìránṣẹ́ mi,+ tí mò ń tì lẹ́yìn! Àyànfẹ́ mi,+ ẹni tí mo* tẹ́wọ́ gbà!+ Mo ti fi ẹ̀mí mi sínú rẹ̀;+Ó máa mú ìdájọ́ òdodo wá fún àwọn orílẹ̀-èdè.+
5 Bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, wò ó! ìkùukùu* tó mọ́lẹ̀ yòò ṣíji bò wọ́n, sì wò ó! ohùn kan dún látinú ìkùukùu náà pé: “Èyí ni Ọmọ mi, àyànfẹ́, ẹni tí mo ti tẹ́wọ́ gbà.+ Ẹ fetí sí i.”+
22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+