ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 13:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ní ti èyí tó bọ́ sórí ilẹ̀ àpáta, òun ló ń gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, tó sì fi ayọ̀ tẹ́wọ́ gbà á lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.+ 21 Síbẹ̀, kò ta gbòǹgbò nínú rẹ̀, àmọ́ ó ń bá a lọ fúngbà díẹ̀, lẹ́yìn tí ìpọ́njú tàbí inúnibíni sì dé nítorí ọ̀rọ̀ náà, ẹsẹ̀kẹsẹ̀ ni a mú un kọsẹ̀.

  • Lúùkù 8:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àwọn ti orí àpáta ni àwọn tó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n fi ayọ̀ tẹ́wọ́ gbà á, àmọ́ àwọn yìí kò ní gbòǹgbò. Wọ́n gbà gbọ́ fúngbà díẹ̀, àmọ́ ní àsìkò ìdánwò, wọ́n yẹsẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́