-
Máàkù 4:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Bákan náà, àwọn yìí ló bọ́ sórí ilẹ̀ àpáta; gbàrà tí wọ́n gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, wọ́n fi ayọ̀ tẹ́wọ́ gbà á.+ 17 Síbẹ̀, wọn ò ta gbòǹgbò nínú ara wọn, àmọ́ wọ́n ń bá a lọ fúngbà díẹ̀; gbàrà tí ìpọ́njú tàbí inúnibíni sì dé nítorí ọ̀rọ̀ náà, wọ́n kọsẹ̀.
-