Léfítíkù 18:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyàwó arákùnrin rẹ lò pọ̀,+ torí ìyẹn máa dójú ti arákùnrin rẹ.* Léfítíkù 20:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Tí ọkùnrin kan bá gba ìyàwó arákùnrin rẹ̀, ohun ìríra ni.+ Ó ti dójú ti* arákùnrin rẹ̀. Kí wọ́n di aláìlọ́mọ.
21 Tí ọkùnrin kan bá gba ìyàwó arákùnrin rẹ̀, ohun ìríra ni.+ Ó ti dójú ti* arákùnrin rẹ̀. Kí wọ́n di aláìlọ́mọ.