15 Nígbà tí Jésù mọ èyí, ó kúrò níbẹ̀. Ọ̀pọ̀ èèyàn tún tẹ̀ lé e,+ ó sì wo gbogbo wọn sàn, 16 àmọ́ ó kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọ́n má ṣe jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ òun,+
29 Ó wá bi wọ́n pé: “Ẹ̀yin ńkọ́, ta lẹ̀ ń sọ pé mo jẹ́?” Pétérù dá a lóhùn pé: “Ìwọ ni Kristi náà.”+30 Ó wá kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọ́n má sọ fún ẹnì kankan nípa òun.+