ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 16:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ó wá kìlọ̀ gidigidi fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn pé kí wọ́n má sọ fún ẹnikẹ́ni pé òun ni Kristi náà.+

  • Máàkù 9:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Bí wọ́n ṣe ń sọ̀ kalẹ̀ bọ̀ látorí òkè náà, ó kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọ́n má sọ ohun tí wọ́n rí fún ẹnì kankan,+ títí dìgbà tí Ọmọ èèyàn bá jí dìde.+

  • Lúùkù 9:21, 22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Àmọ́ ó kìlọ̀ fún wọn gidigidi, ó sọ fún wọn pé kí wọ́n má sọ èyí fún ẹnì kankan,+ 22 ó sì sọ pé: “Ọmọ èèyàn gbọ́dọ̀ jìyà púpọ̀, àwọn àgbààgbà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin máa kọ̀ ọ́, wọ́n máa pa á,+ a sì máa jí i dìde ní ọjọ́ kẹta.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́