Jẹ́nẹ́sísì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+ Éfésù 5:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 “Torí èyí, ọkùnrin á fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèèjì á sì di ara kan.”+
24 Ìdí nìyẹn tí ọkùnrin á ṣe fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, wọ́n á sì di ara kan.+
31 “Torí èyí, ọkùnrin á fi bàbá rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, á sì fà mọ́* ìyàwó rẹ̀, àwọn méjèèjì á sì di ara kan.”+