Jòhánù 13:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, tí èmi, tí mo jẹ́ Olúwa àti Olùkọ́, bá fọ ẹsẹ̀ yín,+ ó yẹ* kí ẹ̀yin náà máa fọ ẹsẹ̀ ara yín.+ Fílípì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó tì o, àmọ́ ó fi gbogbo ohun tó ní sílẹ̀, ó gbé ìrísí ẹrú wọ̀,+ ó sì di èèyàn.*+
14 Torí náà, tí èmi, tí mo jẹ́ Olúwa àti Olùkọ́, bá fọ ẹsẹ̀ yín,+ ó yẹ* kí ẹ̀yin náà máa fọ ẹsẹ̀ ara yín.+