Jeremáyà 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá gbé èéhù* kan tó jẹ́ olódodo dìde fún Dáfídì.+ Ọba kan máa jẹ,+ á sì fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà, á dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, á sì ṣe òdodo ní ilẹ̀ náà.+ Róòmù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 nípa Ọmọ rẹ̀, tó jáde wá látinú ọmọ* Dáfídì+ nípa ti ara,
5 “Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Jèhófà wí, “tí màá gbé èéhù* kan tó jẹ́ olódodo dìde fún Dáfídì.+ Ọba kan máa jẹ,+ á sì fi ìjìnlẹ̀ òye hùwà, á dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, á sì ṣe òdodo ní ilẹ̀ náà.+