Àìsáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí. Àìsáyà 11:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìbẹ̀rù Jèhófà máa jẹ́ ìdùnnú rẹ̀.+ Kò ní gbé ìdájọ́ rẹ̀ ka ohun tó fojú rí,Kò sì ní gbé ìbáwí rẹ̀ ka ohun tó fetí gbọ́ lásán.+ 4 Ó máa dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bó ṣe tọ́,*Ó sì máa fi òtítọ́ báni wí torí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ tó wà ní ayé. Ó máa fi ọ̀pá ẹnu rẹ̀ lu ayé,+Ó sì máa fi èémí* ètè rẹ̀ pa ẹni burúkú.+ Àìsáyà 32:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wò ó! Ọba+ kan máa jẹ fún òdodo,+Àwọn ìjòyè sì máa ṣàkóso fún ìdájọ́ òdodo.
7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.
3 Ìbẹ̀rù Jèhófà máa jẹ́ ìdùnnú rẹ̀.+ Kò ní gbé ìdájọ́ rẹ̀ ka ohun tó fojú rí,Kò sì ní gbé ìbáwí rẹ̀ ka ohun tó fetí gbọ́ lásán.+ 4 Ó máa dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bó ṣe tọ́,*Ó sì máa fi òtítọ́ báni wí torí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ tó wà ní ayé. Ó máa fi ọ̀pá ẹnu rẹ̀ lu ayé,+Ó sì máa fi èémí* ètè rẹ̀ pa ẹni burúkú.+