-
Àìsáyà 61:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
61 Ẹ̀mí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wà lára mi,+
Torí Jèhófà ti yàn mí kí n lè kéde ìhìn rere fún àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+
Ó rán mi láti di ọgbẹ́ àwọn tó ní ọgbẹ́ ọkàn,
Láti kéde òmìnira fún àwọn ẹrú,
Pé ojú àwọn ẹlẹ́wọ̀n sì máa là rekete,+
-
Éfésù 2:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó sì wá kéde ìhìn rere àlàáfíà fún ẹ̀yin tí ẹ jìnnà réré àti àlàáfíà fún àwọn tó wà nítòsí,
-
-
-