Lúùkù 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú, tí wọ́n ń pè ní Ìrékọjá,+ ti ń sún mọ́lé.+ Lúùkù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tó di ọjọ́ àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú, tí wọ́n gbọ́dọ̀ fi ẹran Ìrékọjá rúbọ,+