-
Ẹ́kísódù 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Kí ẹ máa rántí ọjọ́ yìí, kí ẹ sì máa ṣe ayẹyẹ rẹ̀, kó jẹ́ àjọyọ̀ sí Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín. Ẹ máa pa àjọyọ̀ náà mọ́, ó ti di òfin fún yín títí láé.
-
-
Ẹ́kísódù 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Kí ẹ jẹ búrẹ́dì aláìwú láti alẹ́ ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kìíní títí di alẹ́ ọjọ́ kọkànlélógún oṣù náà.+
-