ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 26:61
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 61 wọ́n sọ pé: “Ọkùnrin yìí sọ pé, ‘Mo lè wó tẹ́ńpìlì Ọlọ́run palẹ̀, kí n sì fi ọjọ́ mẹ́ta kọ́ ọ.’”+

  • Máàkù 15:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àwọn tó ń kọjá lọ ń bú u, wọ́n sì ń mi orí wọn,+ wọ́n ń sọ pé: “Ṣíọ̀! Ìwọ tí o fẹ́ wó tẹ́ńpìlì palẹ̀, kí o sì fi ọjọ́ mẹ́ta kọ́ ọ,+

  • Jòhánù 2:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Jésù dá wọn lóhùn pé: “Ẹ wó tẹ́ńpìlì yìí lulẹ̀, màá sì fi ọjọ́ mẹ́ta kọ́ ọ.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́