Sáàmù 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+ Sáàmù 109:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Mo ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe yẹ̀yẹ́.+ Tí wọ́n bá rí mi, ṣe ni wọ́n ń mi orí.+ Àìsáyà 53:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un,+Ọkùnrin tó mọ bí ìrora ṣe ń rí,* tó sì mọ àìsàn dunjú. Ó dà bí ẹni pé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wa.* Wọ́n kórìíra rẹ̀, a sì kà á sí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan.+
3 Àwọn èèyàn kórìíra rẹ̀, wọ́n sì yẹra fún un,+Ọkùnrin tó mọ bí ìrora ṣe ń rí,* tó sì mọ àìsàn dunjú. Ó dà bí ẹni pé ojú rẹ̀ pa mọ́ fún wa.* Wọ́n kórìíra rẹ̀, a sì kà á sí ẹni tí kò já mọ́ nǹkan kan.+