Mátíù 27:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Wò ó! aṣọ ìdábùú ibi mímọ́+ ya sí méjì,+ látòkè dé ìsàlẹ̀,+ ilẹ̀ mì tìtì, àwọn àpáta sì là. Lúùkù 23:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 torí pé oòrùn ò ràn; aṣọ ìdábùú ibi mímọ́+ wá ya délẹ̀ ní àárín.+ Hébérù 10:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Torí náà, ẹ̀yin ará, nígbà tó jẹ́ pé a ní ìgboyà* láti wá sí ọ̀nà tó wọnú ibi mímọ́+ nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀ Jésù, 20 èyí tó ṣí sílẹ̀* fún wa bí ọ̀nà tuntun, tó sì jẹ́ ọ̀nà ìyè tó la aṣọ ìdábùú kọjá,+ ìyẹn ẹran ara rẹ̀,
19 Torí náà, ẹ̀yin ará, nígbà tó jẹ́ pé a ní ìgboyà* láti wá sí ọ̀nà tó wọnú ibi mímọ́+ nípasẹ̀ ẹ̀jẹ̀ Jésù, 20 èyí tó ṣí sílẹ̀* fún wa bí ọ̀nà tuntun, tó sì jẹ́ ọ̀nà ìyè tó la aṣọ ìdábùú kọjá,+ ìyẹn ẹran ara rẹ̀,