-
Ìṣe 13:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Àmọ́ bí Jòhánù ṣe ń parí iṣẹ́ rẹ̀ lọ, ó ń sọ pé: ‘Ta ni ẹ rò pé mo jẹ́? Èmi kọ́ ni ẹni náà. Àmọ́, ẹ wò ó! Ẹnì kan ń bọ̀ lẹ́yìn mi tí mi ò tó bàtà ẹsẹ̀ rẹ̀ tú.’+
-