ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóẹ́lì 2:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Lẹ́yìn ìyẹn, èmi yóò tú ẹ̀mí mi + sára onírúurú èèyàn,

      Àwọn ọmọ yín lọ́kùnrin àti lóbìnrin yóò sì máa sọ tẹ́lẹ̀,

      Àwọn àgbà ọkùnrin yín yóò máa lá àlá.

      Àwọn ọ̀dọ́kùnrin yín yóò sì máa rí ìran.+

  • Ìṣe 2:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ní ọjọ́ Àjọyọ̀ Pẹ́ńtíkọ́sì,+ gbogbo wọn wà níbì kan náà, bí àjọyọ̀ náà ṣe ń lọ lọ́wọ́.

  • Ìṣe 2:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 gbogbo wọn wá kún fún ẹ̀mí mímọ́,+ wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í sọ oríṣiríṣi èdè,* bí ẹ̀mí ṣe mú kí wọ́n máa sọ̀rọ̀.+

  • Ìṣe 11:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ni mo bá rántí ọ̀rọ̀ tí Olúwa máa ń sọ, pé: ‘Jòhánù fi omi batisí,+ àmọ́ a ó fi ẹ̀mí mímọ́ batisí yín.’+

  • 1 Kọ́ríńtì 12:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Nítorí ipasẹ̀ ẹ̀mí kan ni a batisí gbogbo wa sínú ara kan, ì báà jẹ́ Júù tàbí Gíríìkì, ẹrú tàbí òmìnira, a sì mú kí gbogbo wa gba* ẹ̀mí kan.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́