-
Mátíù 21:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Torí Jòhánù wá sọ́dọ̀ yín ní ọ̀nà òdodo, àmọ́ ẹ ò gbà á gbọ́. Ṣùgbọ́n àwọn agbowó orí àti àwọn aṣẹ́wó gbà á gbọ́,+ kódà nígbà tí ẹ rí èyí, ẹ ò pèrò dà lẹ́yìn náà kí ẹ lè gbà á gbọ́.
-
-
Lúùkù 7:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 (Nígbà tí gbogbo èèyàn àti àwọn agbowó orí gbọ́ èyí, wọ́n kéde pé olódodo ni Ọlọ́run, torí Jòhánù ti ṣe ìrìbọmi fún wọn.+
-