Mátíù 3:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Jùdíà àti gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká máa ń lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ 6 ó ń ṣèrìbọmi* fún wọn ní odò Jọ́dánì,+ wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn ní gbangba. Lúùkù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kódà, àwọn agbowó orí wá, kí wọ́n lè ṣèrìbọmi,+ wọ́n sì sọ fún un pé: “Olùkọ́, kí ni ká ṣe?”
5 Àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù àti gbogbo Jùdíà àti gbogbo ìgbèríko tó yí Jọ́dánì ká máa ń lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ 6 ó ń ṣèrìbọmi* fún wọn ní odò Jọ́dánì,+ wọ́n sì ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn ní gbangba.