Dáníẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo wá gbọ́ ohùn èèyàn kan láàárín Úláì,+ ó sì ké jáde pé: “Gébúrẹ́lì,+ jẹ́ kí ẹni yẹn lóye ohun tó rí.”+ Lúùkù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Èmi ni Gébúrẹ́lì,+ tó ń dúró nítòsí, níwájú Ọlọ́run,+ a rán mi láti bá ọ sọ̀rọ̀, kí n sì kéde ìhìn rere yìí fún ọ.
16 Mo wá gbọ́ ohùn èèyàn kan láàárín Úláì,+ ó sì ké jáde pé: “Gébúrẹ́lì,+ jẹ́ kí ẹni yẹn lóye ohun tó rí.”+
19 Áńgẹ́lì náà sọ fún un pé: “Èmi ni Gébúrẹ́lì,+ tó ń dúró nítòsí, níwájú Ọlọ́run,+ a rán mi láti bá ọ sọ̀rọ̀, kí n sì kéde ìhìn rere yìí fún ọ.