Diutarónómì 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+ Jòhánù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Obìnrin náà sọ fún un pé: “Ọ̀gá, mo rí i pé wòlíì ni ọ́.+ Jòhánù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí àwọn èèyàn rí iṣẹ́ àmì tó ṣe, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ó dájú pé Wòlíì tí wọ́n ní ó máa wá sí ayé nìyí.”+ Jòhánù 7:40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 Àwọn kan láàárín èrò tí wọ́n gbọ́ àwọn ọ̀rọ̀ yìí bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Wòlíì náà nìyí lóòótọ́.”+
15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+
14 Nígbà tí àwọn èèyàn rí iṣẹ́ àmì tó ṣe, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ó dájú pé Wòlíì tí wọ́n ní ó máa wá sí ayé nìyí.”+