Mátíù 10:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ mi níwájú àwọn èèyàn, èmi náà máa sẹ́ ẹ níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+ Máàkù 8:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Torí ẹnikẹ́ni tó bá tijú èmi àti àwọn ọ̀rọ̀ mi nínú ìran alágbèrè* àti ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí, Ọmọ èèyàn náà máa tijú rẹ̀+ nígbà tó bá dé nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì mímọ́.”+ 2 Tímótì 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 tí a bá ń fara dà á nìṣó, a tún jọ máa jọba;+ tí a bá sẹ́ ẹ, òun náà máa sẹ́ wa;+
38 Torí ẹnikẹ́ni tó bá tijú èmi àti àwọn ọ̀rọ̀ mi nínú ìran alágbèrè* àti ẹlẹ́ṣẹ̀ yìí, Ọmọ èèyàn náà máa tijú rẹ̀+ nígbà tó bá dé nínú ògo Baba rẹ̀ pẹ̀lú àwọn áńgẹ́lì mímọ́.”+