ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 24:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Àmọ́ ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+

  • Róòmù 5:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Kì í ṣe ìyẹn nìkan, àmọ́ ẹ jẹ́ ká máa yọ̀* nígbà tí a bá wà nínú ìpọ́njú,+ torí a mọ̀ pé ìpọ́njú ń mú ìfaradà wá;+ 4 ìfaradà ní tirẹ̀ ń mú ìtẹ́wọ́gbà wá;+ ìtẹ́wọ́gbà sì ń mú ìrètí wá,+

  • Hébérù 10:36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Nítorí ẹ nílò ìfaradà,+ pé lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kí ẹ lè rí ohun tí ó ṣèlérí náà gbà.

  • 2 Pétérù 1:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nítorí èyí, ẹ sa gbogbo ipá yín+ láti fi ìwà mímọ́ kún ìgbàgbọ́ yín,+ ìmọ̀ kún ìwà mímọ́ yín,+ 6 ìkóra-ẹni-níjàánu kún ìmọ̀ yín, ìfaradà kún ìkóra-ẹni-níjàánu yín,+ ìfọkànsin Ọlọ́run+ kún ìfaradà yín,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́