Mátíù 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi,+ ṣùgbọ́n ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+ Máàkù 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+ Àmọ́ ẹni tó bá fara dà á* dé òpin+ máa rí ìgbàlà.+ Lúùkù 21:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Tí ẹ bá ní ìfaradà, ẹ máa lè pa ẹ̀mí yín mọ́.*+ Hébérù 10:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Nítorí ẹ nílò ìfaradà,+ pé lẹ́yìn tí ẹ ti ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run, kí ẹ lè rí ohun tí ó ṣèlérí náà gbà.
22 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi,+ ṣùgbọ́n ẹni tó bá fara dà á* dé òpin máa rí ìgbàlà.+
13 Gbogbo èèyàn sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+ Àmọ́ ẹni tó bá fara dà á* dé òpin+ máa rí ìgbàlà.+