ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 27:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Àmọ́ àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà rọ àwọn èrò náà pé kí wọ́n sọ pé Bárábà ni àwọn fẹ́,+ àmọ́ kí wọ́n pa Jésù.+ 21 Gómìnà dá wọn lóhùn pé: “Èwo nínú àwọn méjèèjì lẹ fẹ́ kí n tú sílẹ̀ fún yín?” Wọ́n sọ pé: “Bárábà.”

  • Máàkù 15:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àmọ́ àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò náà sókè pé kí wọ́n ní kó tú Bárábà sílẹ̀ fún àwọn dípò rẹ̀.+

  • Jòhánù 18:40
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 40 Wọ́n bá tún kígbe pé: “A ò fẹ́ ọkùnrin yìí, Bárábà la fẹ́!” Àmọ́ olè ni Bárábà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́