Àìsáyà 11:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìkookò máa bá ọ̀dọ́ àgùntàn gbé fúngbà díẹ̀,+Àmọ̀tẹ́kùn máa dùbúlẹ̀ ti ọmọ ewúrẹ́,Ọmọ màlúù, kìnnìún* àti ẹran tó sanra á jọ wà pa pọ̀;*+Ọmọ kékeré á sì máa dà wọ́n. Àìsáyà 35:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Aginjù àti ilẹ̀ tí kò lómi máa yọ̀,+Aṣálẹ̀ tó tẹ́jú máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa yọ ìtànná bíi sáfúrónì.+ Àìsáyà 65:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+ Ìṣe 24:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Mo ní ìrètí nínú Ọlọ́run, ìrètí tí àwọn ọkùnrin yìí náà ní, pé àjíǹde+ àwọn olódodo àti àwọn aláìṣòdodo+ yóò wà. Ìfihàn 21:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo rí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+ torí ọ̀run tó wà tẹ́lẹ̀ àti ayé tó wà tẹ́lẹ̀ ti kọjá lọ,+ kò sì sí òkun mọ́.+
6 Ìkookò máa bá ọ̀dọ́ àgùntàn gbé fúngbà díẹ̀,+Àmọ̀tẹ́kùn máa dùbúlẹ̀ ti ọmọ ewúrẹ́,Ọmọ màlúù, kìnnìún* àti ẹran tó sanra á jọ wà pa pọ̀;*+Ọmọ kékeré á sì máa dà wọ́n.
35 Aginjù àti ilẹ̀ tí kò lómi máa yọ̀,+Aṣálẹ̀ tó tẹ́jú máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ó sì máa yọ ìtànná bíi sáfúrónì.+
17 Torí wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+Àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí,Wọn ò sì ní wá sí ọkàn.+
15 Mo ní ìrètí nínú Ọlọ́run, ìrètí tí àwọn ọkùnrin yìí náà ní, pé àjíǹde+ àwọn olódodo àti àwọn aláìṣòdodo+ yóò wà.
21 Mo rí ọ̀run tuntun àti ayé tuntun;+ torí ọ̀run tó wà tẹ́lẹ̀ àti ayé tó wà tẹ́lẹ̀ ti kọjá lọ,+ kò sì sí òkun mọ́.+