ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 1:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Jẹ́ ká+ dá èèyàn ní àwòrán wa,+ kí wọ́n jọ wá,+ kí wọ́n sì máa jọba lórí àwọn ẹja inú òkun, àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, àwọn ẹran ọ̀sìn, lórí gbogbo ayé àti lórí gbogbo ẹran tó ń rákò tó sì ń rìn lórí ilẹ̀.”+

  • 1 Kọ́ríńtì 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà,+ Baba,+ ọ̀dọ̀ ẹni tí ohun gbogbo ti wá, tí àwa náà sì wà fún un;+ Olúwa kan ló wà, Jésù Kristi, ipasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo fi wà,+ tí àwa náà sì wà nípasẹ̀ rẹ̀.

  • Kólósè 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 nítorí ipasẹ̀ rẹ̀ ni a dá gbogbo ohun mìíràn ní ọ̀run àti ní ayé, àwọn ohun tí a lè rí àti àwọn ohun tí a kò lè rí,+ ì báà jẹ́ ìtẹ́ tàbí ipò olúwa tàbí ìjọba tàbí àṣẹ. Gbogbo ohun mìíràn ni a dá nípasẹ̀ rẹ̀+ àti nítorí rẹ̀.

  • Hébérù 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́