Diutarónómì 18:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+ Lúùkù 24:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tí mo bá yín sọ nìyí, nígbà tí mo ṣì wà lọ́dọ̀ yín,+ pé gbogbo ohun tí a kọ nípa mi nínú Òfin Mósè àti nínú ìwé àwọn Wòlíì àti Sáàmù gbọ́dọ̀ ṣẹ.”+ Jòhánù 1:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Fílípì rí Nàtáníẹ́lì,+ ó sì sọ fún un pé: “A ti rí ẹni tí Mósè, nínú Òfin àti àwọn Wòlíì kọ̀wé nípa rẹ̀ pé: Jésù, ọmọ Jósẹ́fù,+ láti Násárẹ́tì.”
15 Jèhófà Ọlọ́run yín máa gbé wòlíì kan bí èmi dìde fún yín láàárín àwọn arákùnrin yín. Ẹ gbọ́dọ̀ fetí sí i.+
44 Lẹ́yìn náà, ó sọ fún wọn pé: “Àwọn ọ̀rọ̀ tí mo bá yín sọ nìyí, nígbà tí mo ṣì wà lọ́dọ̀ yín,+ pé gbogbo ohun tí a kọ nípa mi nínú Òfin Mósè àti nínú ìwé àwọn Wòlíì àti Sáàmù gbọ́dọ̀ ṣẹ.”+
45 Fílípì rí Nàtáníẹ́lì,+ ó sì sọ fún un pé: “A ti rí ẹni tí Mósè, nínú Òfin àti àwọn Wòlíì kọ̀wé nípa rẹ̀ pé: Jésù, ọmọ Jósẹ́fù,+ láti Násárẹ́tì.”