Àìsáyà 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí a ti bí ọmọ kan fún wa,+A ti fún wa ní ọmọkùnrin kan;Àkóso* sì máa wà ní èjìká rẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ á máa jẹ́ Àgbàyanu Agbani-nímọ̀ràn,+ Ọlọ́run Alágbára,+ Baba Ayérayé, Ọmọ Aládé Àlàáfíà. Jòhánù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kò sí èèyàn tó rí Ọlọ́run rí;+ ọlọ́run bíbí kan ṣoṣo+ tó wà ní ẹ̀gbẹ́ Baba*+ ni ẹni tó ṣàlàyé Rẹ̀.+ Fílípì 2:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+
6 Torí a ti bí ọmọ kan fún wa,+A ti fún wa ní ọmọkùnrin kan;Àkóso* sì máa wà ní èjìká rẹ̀.+ Orúkọ rẹ̀ á máa jẹ́ Àgbàyanu Agbani-nímọ̀ràn,+ Ọlọ́run Alágbára,+ Baba Ayérayé, Ọmọ Aládé Àlàáfíà.
18 Kò sí èèyàn tó rí Ọlọ́run rí;+ ọlọ́run bíbí kan ṣoṣo+ tó wà ní ẹ̀gbẹ́ Baba*+ ni ẹni tó ṣàlàyé Rẹ̀.+
5 Ẹ ní èrò yìí nínú yín, irú èyí tí Kristi Jésù náà ní,+ 6 ẹni tó jẹ́ pé, bí ó tiẹ̀ wà ní ìrísí Ọlọ́run,+ kò rò ó rárá pé òun fẹ́ bá Ọlọ́run dọ́gba.+