-
2 Tẹsalóníkà 1:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Torí bẹ́ẹ̀, à ń gbàdúrà fún yín nígbà gbogbo pé kí Ọlọ́run wa kà yín yẹ fún ìpè rẹ̀,+ kó sì fi agbára rẹ̀ ṣe gbogbo ohun rere tó wù ú láṣepé pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ ìgbàgbọ́. 12 Kí a lè yin orúkọ Olúwa wa Jésù lógo nínú yín, kí a sì yin ẹ̀yin náà lógo nínú rẹ̀, nítorí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run wa àti ti Jésù Kristi Olúwa.
-