Mátíù 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Aláyọ̀ ni àwọn tí wọ́n ṣe inúnibíni sí nítorí òdodo,+ torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn. Jémíìsì 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ̀yin ará mi, tí oríṣiríṣi àdánwò bá dé bá yín, ẹ ka gbogbo rẹ̀ sí ayọ̀,+