-
Títù 1:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 sí Títù, ọmọ gidi tí a jọ jẹ́ onígbàgbọ́:
Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti ti Kristi Jésù Olùgbàlà wa máa wà pẹ̀lú rẹ.
-