Sáàmù 97:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 97 Jèhófà ti di Ọba!+ Kí inú ayé máa dùn.+ Kí ọ̀pọ̀ erékùṣù máa yọ̀.+ Àìsáyà 52:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+ Ìfihàn 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Áńgẹ́lì keje fun kàkàkí rẹ̀.+ Àwọn ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ìjọba ayé ti di Ìjọba Olúwa wa+ àti ti Kristi rẹ̀,+ ó sì máa jọba títí láé àti láéláé.”+
7 Wo bí ẹsẹ̀ ẹni tó ń mú ìhìn rere wá ṣe rẹwà tó lórí àwọn òkè,+Ẹni tó ń kéde àlàáfíà,+Ẹni tó ń mú ìhìn rere wá nípa ohun tó sàn,Ẹni tó ń kéde ìgbàlà,Ẹni tó ń sọ fún Síónì pé: “Ọlọ́run rẹ ti di Ọba!”+
15 Áńgẹ́lì keje fun kàkàkí rẹ̀.+ Àwọn ohùn kan ké jáde ní ọ̀run pé: “Ìjọba ayé ti di Ìjọba Olúwa wa+ àti ti Kristi rẹ̀,+ ó sì máa jọba títí láé àti láéláé.”+