Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Àkọlé Sí/Ojú Ìwé Tí Wọ́n Kọ Orúkọ Òǹṣèwé Sí
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
A Túmọ̀ Rẹ̀ Látinú Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun ní Èdè Gẹ̀ẹ́sì
—Tí A Tún Ṣe Lọ́dún 2013—
“Ohun tí Jèhófà [יהוה, YHWH] Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘ . . .Wò ó! Mò ń dá ọ̀run tuntun àti ayé tuntun; àwọn ohun àtijọ́ ò ní wá sí ìrántí, wọn ò sì ní wá sí ọkàn.’”
—Àìsáyà 65:13, 17; tún wo 2 Pétérù 3:13.
© 2018
WATCH TOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF PENNSYLVANIA
200 Watchtower Drive
Patterson, NY 12563-9205 U.S.A.
ÀWA ÒǸṢÈWÉ
WATCHTOWER BIBLE AND TRACT SOCIETY OF NEW YORK, INC.
Wallkill, New York, U.S.A.
Ó wà lódindi tàbí lápá kan ní èdè tó ju igba ó lé ọgọ́rin (280) lọ. Tí o bá fẹ́ rí gbogbo èdè tí a ti túmọ̀ rẹ̀ sí, lọ sórí ìkànnì www.jw.org/yo.
Àròpọ̀ Gbogbo Ẹ̀dà Ìtumọ̀ Ayé Tuntun Tí A Ti Tẹ̀ Jáde:
247,913,053 Ẹ̀dà
A Tẹ̀ Ẹ́ ní Ọdún 2024
Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà. Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé ti àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà.
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Yoruba (nwt-YR)
Made in U.S.A.
900 Red Mills Road
Wallkill, NY 12589-5200 U.S.A.