JÓṢÚÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  
-  2  - 
- Jóṣúà rán amí méjì lọ sí Jẹ́ríkò (1-3) 
- Ráhábù fi àwọn amí pa mọ́ (4-7) 
- Wọ́n ṣèlérí fún Ráhábù (8-21a) 
- Àwọn amí pa dà sọ́dọ̀ Jóṣúà (21b-24) 
 
-  3  
-  4  
-  5  - 
- Wọ́n dádọ̀dọ́ ní Gílígálì (1-9) 
- Wọ́n ṣe Ìrékọjá; mánà ò rọ̀ mọ́ (10-12) 
- Olórí àwọn ọmọ ogun Jèhófà (13-15) 
 
-  6  
-  7  - 
- Wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì ní ìlú Áì (1-5) 
- Àdúrà Jóṣúà (6-9) 
- Ẹ̀ṣẹ̀ mú kí wọ́n ṣẹ́gun Ísírẹ́lì (10-15) 
- Àṣírí Ákánì tú, wọ́n sì sọ ọ́ lókùúta (16-26) 
 
-  8  - 
- Jóṣúà ní kí wọ́n lúgọ láti gbéjà ko ìlú Áì (1-13) 
- Wọ́n ṣẹ́gun ìlú Áì (14-29) 
- Wọ́n ka Òfin ní Òkè Ébálì (30-35) 
 
-  9  - 
- Àwọn ará Gíbíónì dọ́gbọ́n wá àlàáfíà (1-15) 
- Àṣírí àwọn ará Gíbíónì tú (16-21) 
- Àwọn ará Gíbíónì á máa ṣẹ́gi, wọ́n á sì máa pọnmi (22-27) 
 
- 10  - 
- Ísírẹ́lì gbèjà Gíbíónì (1-7) 
- Jèhófà jà fún Ísírẹ́lì (8-15) 
- Wọ́n pa ọba márààrún tó gbéjà kò wọ́n (16-28) 
- Wọ́n gba àwọn ìlú tó wà ní gúúsù (29-43) 
 
- 11  
- 12  
- 13  - 
- Àwọn ilẹ̀ tí wọn ò tíì gbà (1-7) 
- Wọ́n pín ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn Jọ́dánì (8-14) 
- Ogún Rúbẹ́nì (15-23) 
- Ogún Gádì (24-28) 
- Ogún Mánásè ní ìlà oòrùn (29-32) 
- Jèhófà ni ogún àwọn ọmọ Léfì (33) 
 
- 14  
- 15  
- 16  
- 17  
- 18  
- 19  
- 20  
- 21  
- 22  - 
- Àwọn ẹ̀yà tó wà ní ìlà oòrùn pa dà sílé (1-8) 
- Wọ́n mọ pẹpẹ sí Jọ́dánì (9-12) 
- Wọ́n ṣàlàyé ohun tí pẹpẹ náà túmọ̀ sí (13-29) 
- Wọ́n yanjú ọ̀rọ̀ náà (30-34) 
 
- 23  
- 24  - 
- Jóṣúà sọ ìtàn Ísírẹ́lì (1-13) 
- Ó rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n sin Jèhófà (14-24) 
- Jóṣúà bá Ísírẹ́lì dá májẹ̀mú (25-28) 
- Jóṣúà kú, wọ́n sì sin ín (29-31) 
- Wọ́n sin egungun Jósẹ́fù sí Ṣékémù (32) 
- Élíásárì kú, wọ́n sì sin ín (33)