1 SÁMÚẸ́LÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
-  1  - 
- Ẹlikénà àti àwọn ìyàwó rẹ̀ (1-8) 
- Hánà tó jẹ́ àgàn gbàdúrà kó lè rọ́mọ bí (9-18) 
- Ó bí Sámúẹ́lì, ó sì fi í fún Jèhófà (19-28) 
 
-  2  
-  3  
-  4  
-  5  
-  6  
-  7  - 
- Àpótí náà dé Kiriati-jéárímù (1) 
- Sámúẹ́lì rọ̀ wọ́n pé: ‘Ẹ sin Jèhófà nìkan ṣoṣo’ (2-6) 
- Ísírẹ́lì ṣẹ́gun ní Mísípà (7-14) 
- Sámúẹ́lì ṣe onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì (15-17) 
 
-  8  
-  9  
- 10  
- 11  
- 12  
- 13  - 
- Sọ́ọ̀lù yan àwọn ọmọ ogun (1-4) 
- Sọ́ọ̀lù kọjá àyè rẹ̀ (5-9) 
- Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-14) 
- Ísírẹ́lì kò ní àwọn ohun ìjà (15-23) 
 
- 14  - 
- Àṣeyọrí tí Jónátánì ṣe ní Míkímáṣì (1-14) 
- Ọlọ́run lé àwọn ọ̀tá Ísírẹ́lì lọ (15-23) 
- Ẹ̀jẹ́ tí Sọ́ọ̀lù jẹ́ láìronú jinlẹ̀ (24-46) 
- Àwọn ogun tí Sọ́ọ̀lù jà; ìdílé rẹ̀ (47-52) 
 
- 15  - 
- Àìgbọ́ràn mú kí Sọ́ọ̀lù dá Ágágì sí (1-9)  
- Sámúẹ́lì bá Sọ́ọ̀lù wí (10-23) 
- Ọlọ́run kọ Sọ́ọ̀lù lọ́ba (24-29) 
- Sámúẹ́lì pa Ágágì (30-35) 
 
- 16  - 
- Sámúẹ́lì fòróró yan Dáfídì láti jọba lẹ́yìn Sọ́ọ̀lù (1-13) 
- Ẹ̀mí Ọlọ́run kúrò lára Sọ́ọ̀lù (14-17) 
- Dáfídì di ẹni tó ń ta háàpù fún Sọ́ọ̀lù (18-23) 
 
- 17  
- 18  - 
- Dáfídì àti Jónátánì di ọ̀rẹ́ (1-4) 
- Sọ́ọ̀lù ń jowú torí pé Dáfídì ń ṣẹ́gun (5-9) 
- Sọ́ọ̀lù gbìyànjú láti pa Dáfídì (10-19) 
- Dáfídì fẹ́ Míkálì ọmọ Sọ́ọ̀lù (20-30) 
 
- 19  
- 20  
- 21  
- 22  - 
- Dáfídì ní Ádúlámù àti Mísípè (1-5) 
- Sọ́ọ̀lù ní kí wọ́n pa àwọn àlùfáà tó wà ní Nóbù (6-19) 
- Ábíátárì sá àsálà (20-23) 
 
- 23  - 
- Dáfídì gba ìlú Kéílà sílẹ̀ (1-12) 
- Sọ́ọ̀lù lépa Dáfídì (13-15) 
- Jónátánì fún Dáfídì lókun (16-18) 
- Díẹ̀ ló kù kí ọwọ́ Sọ́ọ̀lù tẹ Dáfídì (19-29) 
 
- 24  
- 25  - 
- Ikú Sámúẹ́lì (1) 
- Nábálì kan àwọn ọkùnrin Dáfídì lábùkù (2-13) 
- Ábígẹ́lì hùwà ọgbọ́n (14-35) 
- Jèhófà kọ lu Nábálì tó jẹ́ òmùgọ̀ (36-38) 
- Ábígẹ́lì di ìyàwó Dáfídì (39-44) 
 
- 26  
- 27  
- 28  
- 29  
- 30  - 
- Àwọn ọmọ Ámálékì wá kó ẹrù ní Síkílágì, wọ́n sì dáná sun ún (1-6) 
- Dáfídì ṣẹ́gun àwọn ọmọ Ámálékì (7-31) - 
- Dáfídì gba àwọn tí wọ́n kó lẹ́rú pa dà (18, 19) 
- Ìlànà tí Dáfídì fi lélẹ̀ lórí pípín ẹrù ogun (23, 24) 
 
 
- 31