Ojú ìwé 2
Pílánẹ́ẹ̀tì Wa Tí À Ń Wu Léwu A Ha Lè Gbà Á Là Bí? 3-14
Ìbàyíkájẹ́ ń ha pílánẹ́ẹ̀tì wa lọ́rùn, wọ́n ń fi igbó píparun gba aṣọ lára rẹ̀, wọ́n sì fi ìlò yàwàlù jẹ ìfun àti ẹ̀dọ̀ rẹ̀ tán. Ìrètí kan ha wà fún pílánẹ́ẹ̀tì wa tí à ń wu léwu lọ́jọ́ ọ̀la bí?
Ṣọ́ọ̀ṣì Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì Ilẹ̀ Gíríìkì —Ìsìn Tí Ó Pín Yẹ́lẹyẹ̀lẹ 15
Ọ̀jọ̀gbọ́n yunifásítì kan ní ilẹ̀ Gíríìkì sọ pé: “Ṣọ́ọ̀ṣì Ilẹ̀ Gíríìkì ti fà ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.” Kí ló fà á? Kí sì ni ìyọrísí rẹ̀?
Ibùdókọ̀ Òfuurufú “Kanku”—A Rí I, Àmọ́ A Kì í Gbúròó Rẹ̀ 24
Òtítọ́ ni—ibùdókọ̀ òfuurufú kan tí a lè lò ní gbogbo ìgbà láìfa ìbínú!
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Láti inú ìwé The Pictorial History of the World
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
Ẹ̀yìn ìwé: Ọmọ tí ó wà láàárín ìdọ̀tí: Fọ́tò: Casas, Godo-Foto