Ojú ìwé 2
Ìgbàṣọmọ Ayọ̀ àti Ìpèníjà Rẹ̀ 3-10
Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ àwọn ọmọ ní ń sunkún òbí káàkiri àgbáyé. Ṣíṣí ilé rẹ—àti ọkàn-àyà rẹ—sílẹ̀ fún ọmọ kan lè mú ayọ̀ ńláǹlà wá, àmọ́ o ní láti múra sílẹ̀ ní ti gidi láti kojú àwọn ìpèníjà tí ó lè dìde pẹ̀lú. Ìgbàṣọmọ ha tọ́ sí ọ bí?
Aláàbọ̀ Ara —Tí Ó Sì Tún Lè Wakọ̀ 11
Wíwa ọkọ̀ lè rọrùn fún ọ, àmọ́ báwo ni ó ṣe ṣeé ṣe fún àwọn tí wọ́n gbára lé ọ̀pá ìtisẹ̀ tàbí kẹ̀kẹ́ arọ láti máa wakọ̀?
Àwọn Òkè Ayọnáyèéfín —Ìwọ́ Ha Wà Nínú Ewu Bí? 15
Mímójú dé ibi ọ̀kan lára àfihàn agbára àdánidá kíkàmàmà jù lọ ní orí ilẹ̀-ayé.