Ojú ìwé 2
Nígbà Tí Fífi Ìbálòpọ̀ Fòòró Ẹni Kì Yóò Sí Mọ́! 3-10
Ibi iṣẹ́ ti di ohun tí ń kó jìnnìjìnnì bá ọ̀pọ̀ àwọn obìnrin. Àwọn ọ̀rọ̀ àìnítìjú, amúniròròkurò máa ń bá ìkọlù òjijì tí ń tẹ́ni lógo náà rìn. Ìsapá àwọn agbanisíṣẹ́ àti yíyíjú sí àwọn ilé ẹjọ́ ti mú àwọn ìyọrísí rere díẹ̀ wá. Àwọn obìnrin Kristian ti rí i pé ó máa ń ṣèrànwọ́ láti fi àwọn ìlànà Bibeli sílò nínú ìwọṣọ àti ìwà wọn.
Irù—Ṣé Ègún Ló Jẹ́ fún Áfíríkà? 11
Ọ̀tá apániláyà ni irù, àmọ́ ṣé bẹ́ẹ̀ ló burú tó ni?
Lahar—Àtubọ̀tán Òkè Ńlá Pinatubo 17
Lahar jẹ́ àwọn ẹrẹ̀ àti ìgẹ̀dẹ̀gẹ́dẹ̀ òkè ayọnáyèéfín tí ó ki gan-an tí wọ́n fi dà bíi kọnnkéré tí ń ṣàn. Nítorí náà, aṣèparun ni wọ́n!
[Àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
©Martin Dohrn, The National Audubon Society Collection/PR