Ojú ìwé 2
Ṣé Ìsinmi Lò Ń Lọ? Ohun Tó Yẹ Kí O Mọ̀ 3-10
Ta ni kì í gbádùn lílọ fún ìsinmi? Mọ̀ nípa bí wíwà lójúfò sí àwọn ewu tí ó lè ṣẹlẹ̀ ṣe lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti gbádùn ìsinmi láìkábàámọ̀.
Kí Ló Dé Tí N Kò Lè Kẹ́kọ̀ọ́? 11
Ó tó ìpín 10 nínú ọgọ́rùn-ún lára gbogbo àwọn ọmọdé tí wọn lè ní ìṣòro àtikẹ́kọ̀ọ́. Kí ni wọ́n lè ṣe láti kojú rẹ̀?
Àrùn Lyme—O Ha Wà Nínú Ewu Bí? 14
Kí ló lè kó ọ sínú ewu? Àwọn àmì wo ló ní? Báwo ni o ṣe lè dènà kíkó o?